Danilo Türk (pìpè [tyrk]) (ojoibi 19 February, 1952) ni Aare orile-ede Slovenia lowolowo. O je agbejoro ati diplomati.

Danilo Türk
President of Slovenia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
23 December 2007
Alákóso ÀgbàJanez Janša
Borut Pahor
AsíwájúJanez Drnovšek
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kejì 1952 (1952-02-19) (ọmọ ọdún 72)
Maribor, Slovenia (Slovenia)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
(Àwọn) olólùfẹ́Barbara Miklič
Alma materUniversity of Ljubljana
Websitewww.daniloturk.si/