Dáríù 1k Pẹ́rsíà
(Àtúnjúwe láti Darius I of Persia)
Dáríù 1k (èdè Persia atijo: Dārayavahuš) (550 – 486 BCE), to tun je mimo bi Dariu Eninla, lo je oba awon oba Ileobaluaye Akamedi eketa. Dariu lojoba nibe nigba ogo ile yi, nigbana to ni Egypt (Mudrâya)[1], Balochistan, Kurdistan ati awon apa Greece ninu.
Dáríù 1k | |
---|---|
Khshayathiya Khshayathiyanam , King of Kings | |
Orí-ìtẹ́ | Sep 522 BCE to Oct 486 BCE (36 years) |
Orúkọ oyè | Ismael the Pagla |
Ìsìnkú | Naqsh-e Rustam |
Aṣájú | Bardiya |
Arọ́pọ̀ | Xerxes I |
Ìyàwó | Atossa |
Ọmọ | Artobazan, Xerxes |
Ẹbíajọba | Achaemenid Empire |
Bàbá | Hystaspes |
Ìyá | Rhodogune |
Ẹsìn | Zoroastrianism |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2013-09-25. Retrieved 2011-11-07.