Darnley Arthur Alexander

Darnley Arthur Alexander je Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà tele.

Darnley Arthur Alexander

Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà 4k
In office
1975–1979
AsíwájúTaslim Olawale Elias
Arọ́pòAtanda Fatai Williams
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1920-01-28)28 Oṣù Kínní 1920
Saint Lucia
Aláìsí10 February 1989(1989-02-10) (ọmọ ọdún 69)

Eni owo Darnley Alexander, QC, SAN, GCFR (ojo kejidinlogbon osu kinni odun 1920 – ojo kewa osu keji 1989) je adajo ati pelu Olùdájọ́ agba nigbakan ri lori ile ede Nàìjíríà.[1][2]

Alexander je ọmọ bíbí Castries, St Lucia ni ọjọ kejidinlogbon oṣù kínní 1920. O bẹrẹ ìwé kíkà ni ile-iwe giga eyi to wa nilu London níbi tí ọ ti gba oyè amofin ni ọdún 1942. O ṣiṣe gẹgẹ bí olumoran ati òṣèré òfin ni ìlú Jamaica ati adájọ ni Turks and Caicos Islands. O wà sí Nàìjíríà ni ọdún 1957 láti ìwé iransẹ lati owo ìwọ̀ oòrùn, Obafemi Awolowo ti ọ ṣe afilo sí ile iṣẹ amunisin ti London láti ṣe iranwọ fún amofin ;[3] Alexander ṣiṣe ni agbegbe ni orisirisi awọn agbara. O jẹ òṣèré òfin, ìwọ̀ oòrùn, Nàìjíríà lati ọdún 1957-1969 o ṣiṣe bi adari ilé iṣẹ awọn ẹjọ ni ọdún 1958. Ni ọdún 1960, a yàn gẹgẹ bí agbejoro gbogboogbo àti akọwe ti agbegbe ijoba tí ìdájọ ni ọdún 1963, a fún ní òye Queen's Counsel. Ni ọdún 1964, a yàn gẹgẹ bi adájọ ni ile ẹjọ to gaju ni eko, ni ọdún 1969, a yàn gẹgẹ bí adájọ agba ti guusu ila oorun ni awon ipinle Cross River ati Akwa Ibom. A yàn gẹgẹ bí agbejoro to ga ju ni ọdún 1975 lórí àwọn ọmọ ẹgbẹ agba ti ilé ejó. Gẹgẹ bí agbejoro, a fi je oyè láti ọwó Dennis Osadebay láti darí gẹgẹ bí igbimọ òfin tòótọ sínú Owegbe secret cult, o tu ṣiṣe bi alága ilé ejó ti ìbéèrè sinu ayẹwo ti ọ ṣe dédé.[4]

Lẹyìn ífeyinti rẹ, o di alaga egbe ti on mojuto òfin tòótọ ilu Nàìjíríà.



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Okoi Obono-Obla. "The Dawn of another Era in the Judiciary in Cross River State of Nigeria". elombah.com. Retrieved 26 April 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "As Nigeria gets First female Chief Justice: A Profile of Justice Mariam Aloma Muktar". Nigeria Intel. Retrieved 26 April 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Dr. Festus Ajayi, San: Plea Bargain is an Illegal Arrangement". Thisday Newspaper. Retrieved 30 August 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. Kamil, M. (1995). Rendez-vous--: An authorized biography of Chief Justice Mohammed Bello. Ikeja, Lagos, Nigeria: Malthouse Press. pp. 253-254