Dauda Lawal
(ojoibi 2 osu kesan odun 1965) je okunrin banki ati oloselu omo Naijiria ti o je gomina ipinle Zamfara. Wọ́n dìbò yàn án lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) nínú ìdìbò gómìnà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 2023 tí wọ́n ṣẹ́gun Gomina Bello Matawalle ti ẹgbẹ́ òṣèlú APC.