David Khari Webber Chappelle ( /ʃəˈpɛl/; ọjọ́ìbí August 24, 1973) jẹ́ aláwàdà orí-ìtàgé, òṣeré, olùkọ̀wé, àti olóòtú ará Amẹ́ríkà. Chappelle ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ àwàdà rẹ̀, nínú wọn ni two Ẹ̀bùn Emmy méjì àti Ẹ̀bùn Grammy mẹ́ta, wọ́n tún fún ní Ẹ̀bùn Mark Twain. He is known for his satirical comedy sketch series Chappelle's Show (2003–2006). The series, co-written with Neal Brennan, ran until Chappelle quit the show in the middle of production of the third season. After leaving the show, Chappelle returned to performing stand-up comedy across the U.S.[3] By 2006, Chappelle was called the "comic genius of America" by Esquire[4] and, in 2013, "the best" by a Billboard writer.[5] In 2017, Rolling Stone ranked him No. 9 in their "50 Best Stand Up Comics of All Time."[6]

Dave Chappelle
Dave Chappelle ní oṣù kẹwàá ọdún 2018
Orúkọ àbísọDavid Khari Webber Chappelle
ÌbíOṣù Kẹjọ 24, 1973 (1973-08-24) (ọmọ ọdún 50)
Washington, D.C., U.S.
Medium
  • Stand-up
  • television
  • film
Years active1992–present[1]
Net worth$50 million[2]
Genres
Subject(s)
Spouse
Elaine Erfe (m. 2001)
Ìtọwọ́bọ̀wé


Itokasi àtúnṣe