David Olatunji Abioye je omo Naijiria ti a bi ni March 11,1961o je onigbagbo, onkowe ati oniwaasu; oun niigbakeji adari ijo fun ijo olorun igbagbo aye kaakiri agbaye iyen Living Faith Church. [1] O je bisoobu ati oniwaasu agba ni ijo to wa ni Abuja eyi ti a n pe ni ilu Goseni ti o ni iwon omo ijo oke meji ati abo ti o n josin nibe.[2][3][4]

David Abioye
Ọjọ́ìbíDavid Olatunji Abioye
11 Oṣù Kẹta 1961 (1961-03-11) (ọmọ ọdún 63)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́University of Ilorin
Olólùfẹ́
Mary Abioye (m. 1988)
Àwọn ọmọ3
Websitedavidabioye.org.ng

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bi I si ilu idile kan ni ipinle Kwara.[5] Abioye se igbeyawo pelu arabinrin Mary Abioye; won si bi omo meta: David Jr, Ruth ati Daniel.[6][7] O lo si ile eko giga yunifasiti ti ilu ilorin lati lo ko eko nipa imo ero iyen (mechanical engineering).[8] O sise olumo ni ile eko gbogbo nise ni Auchi iyen (open cast polytechnic,Auchi) ni odun 1985 fun odun kan

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Adekunle. "Love, Forgiveness panaceas to broken marriages, says Abioye". 
  2. "2019: Bishop David Abioye lists ways Nigeria is being islamized by Buhari, tells members who to vote". 
  3. "Interview with Bishop David Abioye, Senior Pastor Of Living Faith Church, Goshen City". Archived from the original on 2018-12-15. Retrieved 2023-12-07. 
  4. "Serving God is not for clerics alone, says Bishop Abioye". 
  5. Kolesnik, Kay (28 December 2017). "Life story of Bishop David Abioye". Legit.ng – Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-16. 
  6. "About Bishop Abioye". Archived from the original on 2020-11-24. Retrieved 2023-12-07. 
  7. "About Bishop Abioye – David Abioye" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-02-16. Retrieved 2022-02-16. 
  8. "Pastor Series 4; David Abioye- Apostolic Humility and Loyalty in the Service of Bishop Oyedepo". ModernGhana. Retrieved 2019-10-28.