David Blackwell
David Harold Blackwell tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹrin ọdún 1919, tí ó ṣaláìsí ní ọdún 2010 jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Statistiki ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifasity Kalifornia ní Berkeley, bẹ́é sì ni orúkọ rẹ̀ wà lára àwọn aropojinle Rao-Blackwell. Wọ́n bi ní agbègbè Centralia, ní ìlú Illinois. Ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti Nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di ìkan lára àwọn Akademi Olomoorile-ede ninu Sayensi, àti Adúláwọ̀ akọ́kọ́ tó kọ́kọ́ di adarí ẹ̀kọ́ ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ UC Betkeley. [1][2]
David Blackwell | |
---|---|
David Harold Blackwell | |
Ìbí | Centralia, Illinois, United States | Oṣù Kẹrin 24, 1919
Aláìsí | July 8, 2010[1] Berkeley, California | (ọmọ ọdún 91)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Pápá | Mathematician |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of California, Berkeley |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Illinois at Urbana-Champaign |
Doctoral advisor | Joseph Leo Doob |
Notable students | Roger J–B Wets |
Ó gbajúmọ̀ fún | Rao–Blackwell theorem Blackwell channel |
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 1935, nigba to je omo odun 16, Blackwell lo si Yunifasiti Illinois ni Urbana-Champaign pelu ero lati di oluko mathimatiki ni ile-eko alakobere. Ni 1938 o gba iwe-eri bachelor ninu mathimatiki, iwe-eri master ni 1939, be sini o di dokita ninu mathimatiki ni 1941 nigba to je omo odun 22, gbogbo won lati Yunifasiti Illinois.[3][4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Sorkin, Michael (July 14, 2010). "David Blackwell fought racism; become world-famous statistician". Saint Louis Post-Dispatch. http://www.stltoday.com/news/local/obituaries/article_8ea41058-5f35-5afa-9c3a-007200c5c179.html.
- ↑ Cattau, Daniel (July 2009). "David Blackwell 'Superstar'". Illinois Alumni (University of Illinois Alumni Association): pp. 32–34.
- ↑ James H. Kessler, J. S. Kidd, Renee A. Kidd. Katherine A. Morin (1996), Distinguished African American Scientists of the 20th Century, Greenwood, ISBN 0897749553
- ↑ Grime, David (July 17, 2007). "David Blackwell, Scholar of Probability, Dies at 91". New York Times. http://www.nytimes.com/2010/07/17/education/17blackwell.html. Retrieved August 22, 2010.