David Uzochukwu

fotogíráfà ọmọ orílẹ̀-èdè Austria tí ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

David Ejikeme Uzochukwu (tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù Kejìlá ọdún 1998) jẹ́ olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Austria àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bákannáà ẹni tí ó jẹ́ wípé àwòrán fọ́tòyíyà ni ó dojú kọ jùlọ. Brussels àti Berlin ni Uzochukwu ń gbé. Ó jẹ́ ókan lára àwọn queer.[1]

David Uzochukwu
Ọjọ́ìbíDavid Ejikeme Uzochukwu
10 Oṣù Kejìlá 1998 (1998-12-10) (ọmọ ọdún 26)
Innsbruck, Austria
Orílẹ̀-èdèAustrian–Nigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèAustrian–Nigerian
Ẹ̀kọ́Humboldt-Universität zu Berlin
Gbajúmọ̀ fúnFọ́tòyíyà
AwardsEyeEm, Flickr's 20 Under 20
WebsiteOfficial website

Ìgbésí ayé àti ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ

àtúnṣe

David Ejikeme Uzochukwu ni wọ́n bí ní Innsbruck, Austria. Ìyá rẹ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Austria nígbàtí bàbá rẹ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Innsbruck ni wọ́n ti tọ́ọ dàgbà kí ó tó wà lọ sí Luxembourg àti Brussels . Láti ìgbà náà ni ó ti ń gbé ní Vienna àti Berlin níbití ó ti gba oyè àkọ́kọ́ lórí àwòrán yíyà nínú philosophy ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Humboldt Yunifásítì tí ó wà ní Berlin.

Iṣẹ́

àtúnṣe

Uzochukwu bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú yíya àwòrán ara ẹni kí ó to dí wípé ó dàgbà sókè síi láti máa ya àwọn àwòrán ní ti ìṣẹ̀dá. Iṣẹ́ fọ́tòyíyà rẹ ma ń dá lórí dídàpọ̀ iṣẹ́ tí ó ti parí mọ́ àwọn àwòrán tí wọ́n fi ara jọ wọn,[2] tí ó jẹ́ pé nígbà gbogbo ni ó ma ń fún àwọn àwòrán ní ìyàsọ́tọ̀ tí ó ma ń dúró lára rẹ ní ìfihàn ara ti èéfín, àwọsánmà, omi àti iná. Àwọn àwòrán rẹ tí ó jẹ́ gidi ma ń ṣe àfihàn, fún àpẹrẹ àwọn àwọsánmà búlúù tí ó di ògiri, àwọn kirisita tí ó lééfòó ní àárín afẹ́fẹ́, Iyanrìn folkano tí ó di oun ìtùnú, tàbí ẹ̀jẹ̀ tí ó yípadà sí ìbòjú.[3]

Nígbàgbogbo ni iṣẹ́ rẹ ma ń darí àwọn àkíyèsí sí orí ẹlẹ́yàmẹyà àti queerness. Ní Amsterdam àì fọjúrí, fún àpẹrẹ ó ṣe àfihàn oríṣiríṣi àwọn fọ́tò tí wọ́n lo àpẹrẹ àwòrán ẹ̀dá omi humanoid tí wọ́n ní àwọn ìyẹ̀, àwọn ìrù, tàbí eyín tí ó mú. Ní ọdún 2019, Uzochukwu tí sọ pé àwọn iṣẹ́ yìí ṣe àfihàn ìgbàsílẹ̀ "dúdú", láti ní érò ìnilára ti ẹlẹ́yàmẹ̀yà tí wọ́n ti pàṣẹ lé lórí, àti láti ṣe rere láìbìkítà.[4][5]

Iṣẹ́ rẹ tuntun tí ó ṣe ni ayẹyẹ ìṣẹ̀dá àwòrán ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àwòrán kọ̀ọ̀kan ń ṣe àpèjúwe lórí 'agbára ìdálọ́wọ́dúró ti àwọn ayàwòrán yìí ma ń sábà ti kí àwọn ǹkan lè ṣẹlẹ̀.[6]

Àwọn tí wọ́n jẹ́ àwòkọ́ṣe fún iṣẹ́ rẹ ni àwọn bíi olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Gregory Crewdson àti ayàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Kenya tí ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà bákannáà, wangechi Mutu, tí àwọn iṣẹ́ wọn jẹmọ́ àwọn ilé-ayé ti ara ẹni tí ó sọ nípa akọ àti abo, ẹlẹ́yàmẹyà, ìtàn àwòrán àti ìdánimọ̀ ara ẹni.[7][8]

Ní ọdún 2016, ọ̀kan nínú àwọn iṣẹ́ rẹ, A Familiar Ruin ni wọ́n ṣe àfihàn rẹ ní BOZAR, tíí ṣe ibi tí wọ́n yá sọ́tọ̀ fún ìtanràn àwòrán gégé bíi ara ipa ti ìṣàfihàn ẹgbẹ́ tí wọ́n pè ní Dey Your Lane!, tí ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Azu Nwagbogu ṣe ìtọ́jú rẹ.

Àwọn ìfihàn (yíyàn)

àtúnṣe
  • FOM Foto Maastricht, 6211-kunskwartier, Maastricht, oṣù kẹjọ ọdún 2014.
  • Flickr Friday: A Living Room, iGNANT, Berlin, oṣù kínní ọdún 2014; co-organised with Fantastic Frank[9]
  • Flickr, 20 Under 20, curated by Vogue photo director Ivan Shaw, Milk Studios, New York, NY, oṣù kẹwàá ọdún 2014[10]
  • The EyeEm World Tour 2015, traveled to Alte Teppichfabrik, ọjọ́ kejìlá sí ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn án ọdún 2014; NUMA, Paris, ọjọ́ kẹtàlá sí ọjọ́ karùndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2014; EyeEm Studio San Francisco, San Francisco, CA, ọjọ́ kẹrìnlá oṣú kọkànlá ọdún 2014; Roppongi Hills, Tokyo, ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n sí ọgbọ́n ọjọ́ oṣù kọkànlá ọdún 2014; Art basel miami, The Lab Miami, Miami, FL, ọjọ́ kínní sí ọjọ́ keje oṣù kejìlá ọdún 2014; Tokyo Institute of Photography, Tokyo, ọjọ́ kẹta sí ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejìlá ọdún 2014; Haus der Universität, Düsseldorf, ọgbọ̀n ọjọ́ oṣú kínní ọdún 2015, as part of Düsseldorf Photo Weekend; Soho House Toronto, Toronto, ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2015; Openhouse Gallery, New York, NY, ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2015[11]
  • Unlocked, curated by Vassilis Zidianakis, ATOPOS Contemporary Visual Culture, Athens, ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejì sí ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin ọdún 2016[12]
  • Africa Salon – mo(ve)ments: African Digital Subjectivities, Yale School of Art, New Haven, CT, ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n sí ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2016
  • Whispering Stills, Never Apart, Montréal, ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹrin sí ọjọ́ kẹsàn án oṣù keje ọdún 2016
  • Dey Your Lane !, curated by Azu Nwagbogu, BOZAR Center for Contemporary Art, Brussels, ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹfà sí ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn án ọdún 2016[13]
  • Lagos Photo Festival, Inherent Risk; Rituals and Performance, curated by Azu Nwagbogu, Eko Hotel & Suites, Victoria Island, Lagos, ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹwàá sí ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kọkànlá ọdún 2016[14]
  • 27th Festival of African, Asian and Latin American Film Cinema, Where Future Beats, curated by Azu Nwagbogu and Maria Pia Bernardoni, Casello Ovest di Porta Venezia, Milano, ọjọ́ kọkàndínlógún sí ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn ún ọdún 2017; co-organised by Lagos Photo Festival, Lagos[15]
  • Portraits, Photo Brussels Festival 02, Hangar, Photo Art Center, Brussels, ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2017 sí ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kínní ọdún 2018
  • Songe du Présent, MuPHo Musée de la photographie de Saint Louis, St Louis, Sénégal, ọjọ́ kẹta sí ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn ún odún 2018; organised on the occasion of Dak'art Biennale 2018[16][17]
  • Innate: Future Blooms (Djeneba Aduayom), La Villa Rouge, Dakar, ọjọ́ kẹta sí ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn ún ọdún 2018; as part of the exhibition Bridge curated by MuPHo Musée de La Photographie de St Louis, on the occasion of Dak'art Biennale 2018
  • Transparent, Kalonoma Festival, Munich, ọjọ́ karùn ún oṣù karùn ún ọdún 2018
  • When Ethics meets Aesthetics, Vogue Italia initiative, Leica Gallery Milano, Milan, ọjọ́ kẹrin sí ogúnjọ́ oṣù kẹfà ọdún 2018
  • Liquid Thunder, An Immersive Soundscape Experience With David Uzochukwu, MONOM, Berlin, ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹwàá ọdún 2019; (solo exhibition with sound installation by William Russell)
  • PhotoVogue Festival 2018, Embracing Diversity, curated by Alessia Glaviano and Francesca Marani, BASE Milano, ọjọ́ kẹrìnlá sí ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2019[18][19][20][21]
  • Unseen Amsterdam, ogúnjọ́ sí ọjọ́ kejìlélógún oṣú kẹsàn án ọdún 2019; represented by Gallery Number 8, Brussels
  • PhotoVogue Festival 2019, A Glitch in the System, curated by Alessia Glaviano and Francesca Marani, BASE Milano, ọjọ́ kẹrìnlá sí ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2018[18][19][20][21]

Iṣẹ́ ṣíṣe rẹ

àtúnṣe

Uzochukwu bẹ̀rẹ̀ síní ya fọ́tò láti ìgbàtí ó ti wà ní èwe. Nígbàtí ó pé ọmọ ọdún mẹ́wàá ó ti mọ fọ́tò yíyà dáradára nítorí pé ó ma ń lo kámẹ́rà ìyá rẹ láti fiya fọ́tò.[22] Ó bẹ̀rẹ̀ pínpín àwọn fọ́tò rẹ káàkiri nígbàtí ó pé ọmọ ọdún mẹ́tàlá.[23] Ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, Uzochukwu ti di ọ̀jọ̀gbọ́n nínú fọ́tò yíyà tí ó sì fi ọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú Iconoclast Image àti Gallery 8.[24] Nígbàtí Uzochukwu di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, FKA Twigs múu lọ sí ìlú Mexico láti lọ ya ìpolongo pàtàkì kan fún Nike.[25]

Uzochukwu ti ṣe àwọn ìpolongo fún àwọn oníbàárà bíi Adobe Photoshop, The Paris Opera (Opéra National de Paris),[26] Dior,[27] Nike,[28] Iris van Herpen,[29] àti World Wildlife Fund[30]. Ó sì tún ti ṣe iṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ayàwòrán bíi FKA Twigs,[31] Ibeyi,[32] Benjamin Clementine,[33] Labrinth,[34] Little Gragon àti Pharell Williams.[35]

Àwọn Ìdánimọ̀

àtúnṣe

Ní ọdún 2014, wọ́n pe Uzochukwu ní EyeEm gẹ́gẹ́ bíi olùyàwòrán tí ó tayọ fún ti ọdún yìí,[36] àti ọ̀kan lára ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti Flick ogún lábẹ́ẹ ogun.[37] Ní ọdún 2015, ó wà lára àwọn díẹ̀ tí wọ́n yàn fún Adobe Photoshop's márùndínlógún lábẹ́ẹ márùndínlógún,[38] ó sì gba àmì ẹ̀yẹ akẹ́kọ̀ọ́ fún fọ́tò yíyà ti Canon x Exhibitr.[39] Ní ọdún 2019, wọ́n yàn án fún CPH:LAB 2019/2020, èyí tíí ṣe ètò ìdàgbàsókè tálẹ̀ntì ti CPH:DOX àjọyọ̀ ìwé ìtàn káríayé Copenhagen.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "It's a pride, pride world". CUB Magazine. 2019-06-08. Archived from the original on 2021-10-19. Retrieved 2021-09-29. 
  2. "From signing with an agent at 16, to shooting for Nike at 17: What…". Creative Lives in Progress. 2018-08-16. Retrieved 2021-09-29. 
  3. "KNOTORYUS talks to David Uzochukwu". KNOTORYUS. 2017-12-04. Retrieved 2021-09-29. 
  4. "Across The Globe: Artist Spotlight #10". Artsy. 2019-09-16. Retrieved 2021-09-29. 
  5. Beckert, Michael (2019-06-25). "What "Pride" Really Means, as Illustrated by 35 Queer Photographers". W Magazine. Retrieved 2021-09-29. 
  6. Elizabeth, Marcia (2019-05-21). "David Uzochukwu’s ‘Pluton’ Celebrates Nigerian Creatives". Bubblegum Club. Retrieved 2021-09-30. 
  7. "Flora Vesterberg". Flora Vesterberg. 2021-09-06. Retrieved 2021-09-30. 
  8. "Wangechi Mutu". Artnet. 1972-06-22. Retrieved 2021-09-30. 
  9. Kurze, Caroline (2014). "A Living Room by iGNANT, x Fantastic Frank". Ignant.com. Retrieved 24 May 2020. 
  10. Tafoya, Angela (16 September 2014). "These 20 Teenagers Are The Future Of Photography". Refinery29.com. Retrieved 24 May 2020. 
  11. "The EyeEm World Tour". 2014. Retrieved 24 May 2020. 
  12. Zidianakis, Vassilis (2016). Unlocked. Athens: ATOPOS Contemporary Visual Culture. 
  13. Staff writer (2016). "17 juni '16 — 04 september '16, Dey Your Lane!, Lagos Variations". Bozar.be. Archived from the original on 27 January 2021. Retrieved 24 May 2020. 
  14. Staff writer (2016). "2016". Lagos Photo Festival. Retrieved 24 May 2020. 
  15. Bernardoni, Maria Pia (2017). "Photo exhibition "Where Future Beats"". Festival Cinema Africano. Retrieved 24 May 2020. 
  16. Mercier, Jeanne (24 January 2018). "Ouverture du MuPho à Saint Louis, premier musée dédié à la photographie au Sénégal". 9 Lives Magazine (in Èdè Faransé). Retrieved 24 May 2020. 
  17. Senegal Black Rainbow (16 May 2018). "Le musée de la photo de St Louis". Senegal Black Rainbow (in Èdè Faransé). Archived from the original on 29 September 2021. Retrieved 24 May 2020. 
  18. 18.0 18.1 "Photo Vogue Festival: Milan, Italy 15–18 November 2018". Shutterhub. 2018. Archived from the original on 10 August 2020. Retrieved 24 May 2020. 
  19. 19.0 19.1 Staff writer (2018). "Photovogue – David Uzochukwu". Vogue. Retrieved 24 May 2020. 
  20. 20.0 20.1 Pelloso, Giovanni. "Photo Vogue Festival 2019". Vivi Milano Corriere. Retrieved 24 May 2020. 
  21. 21.0 21.1 Marani, Francesca (22 May 2018). "When Ethics meets Aesthetics • The exhibition. The opening at Leica Galerie in Milan". Vogue. Retrieved 24 May 2020. 
  22. Day, Today is Art (2014-09-22). "15-Year-Old Photographer's Surreal Portraits Express Powerful Emotions". My Modern Met. Retrieved 2021-09-30. 
  23. "ICONOCLAST AND MONOM PRESENT : AN IMMERSIVE SOUNDSCAPE EXPERIENCE WITH DAVID UZOCHUKWU". monom. 2020-03-10. Retrieved 2021-09-30. 
  24. "Going Pro at 16. An Interview with David Uzochukwu". EyeEm. 2015-01-28. Retrieved 2021-09-30. 
  25. "Meet David Uzochukwu, the photographer behind FKA twigs' Dream Warrior issue". Crack Magazine. Retrieved 2021-09-30. 
  26. Opara, Gabriella (2016-02-26). "Meet David Uzochukwu, The Austro-Nigerian Photographer Who Is Doing Great Things!". Zikoko!. Retrieved 2021-09-30. 
  27. Colomer, Arnau Valls (2021-09-26). "Dior 'Collection' Dir David Uzochukwu Prod ICONOCLAST". Vimeo. Retrieved 2021-09-30. 
  28. "FKA twigs teams up with 17 year old photographer David Uzochukwu for new Nike campaign". It's Nice That. Retrieved 2021-09-30. 
  29. "'Sensory Seas' by David Uzochukwu - News". Iris van Herpen. Retrieved 2021-09-30. 
  30. "Wirz für WWF: Ohne Mutter Natur gibt es keine Zukunft für Menschenkinder". https://www.horizont.net (in Èdè Jámánì). 2017-09-11. Retrieved 2021-09-30.  External link in |website= (help)
  31. "Meet David Uzochukwu, the photographer behind FKA twigs' Dream Warrior issue". Crack Magazine. Retrieved 2021-09-30. 
  32. Vriendt, Mien De (2017-09-02). "De Brusselse tiener bij wie sterren in de rij staan". De Standaard (in Èdè Dọ́ọ̀ṣì). Retrieved 2021-09-30. 
  33. "Benjamin Clementine". Matthew Josephs. Retrieved 2021-09-30. 
  34. Smyth, David (2019-10-25). "Labrinth interview: 'I felt like my crown was becoming a burden'". Evening Standard. Retrieved 2021-09-30. 
  35. "DPG Media Privacy Gate". myprivacy.dpgmedia.be. Retrieved 2021-09-30. 
  36. "O autodidata de 16 anos eleito 'Fotógrafo do Ano'". BBC News Brasil (in Èdè Pọtogí). 2015-11-03. Retrieved 2021-09-30. 
  37. Flickr. 2021-09-30 https://www.flickr.com/photos/20under20. Retrieved 2021-09-30.  Missing or empty |title= (help)
  38. "The Blog". Adobe Blog. 2021-09-24. Retrieved 2021-09-30. 
  39. Fernández, Elisa Sánchez (2016-10-03). "Fotos: Las seis cuentas que seguir en tus redes sociales este octubre". EL PAÍS (in Èdè Sípáníìṣì). Retrieved 2021-09-30.