Dawda Jawara
Dawda Kairaba Jawara, GCMG (ojoibi May 16, 1924) lo je olori akoko orile-ede Gambia, o koko je gege bi Alakoso Agba lati 1962 de 1970 ati gege bi Aare lati 1970 de 1994.
Sir Dawda Jawara | |
---|---|
President of the Gambia | |
In office 24 April 1970 – 22 July 1994 | |
Arọ́pò | Yahya Jammeh |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kàrún 1924 Barajally, MacCarthy Island Division |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People Progressive Party (PPP) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |