Deji Akinwande
Deji Akinwande jẹ́ ọmọ orílẹ̀ Naijiria tó sì tún tan mọ́ ilẹ̀ America. Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Electrical and Computer Engineering tó sì tún ní àsopọ̀ mọ́ Materials Science ní University of Texas at Austin.[1] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Presidential Early Career Award for Scientists and Engineers ní ọdún 2016 láti ọwọ́ Barack Obama.[1] Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ American Physical Society, African Academy of Sciences, Materials Research Society (MRS), àti IEEE.
Deji Akinwande | |
---|---|
Akinwande shakes hands with President Barack Obama, while receiving the PECASE in 2016 | |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Texas at Austin |
Ibi ẹ̀kọ́ | Stanford University Case Western Reserve University |
Doctoral advisor | H.-S. Philip Wong |
Ó gbajúmọ̀ fún | 2D materials, flexible and wearable nanoelectronics, nanotechnology, STEM education |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | PECASE, given in 2016 Fellow of American Physical Society Fellow of IEEE. Fellow of the MRS. |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Deji Akinwande | Texas ECE - Electrical & Computer Engineering at UT Austin". www.ece.utexas.edu. Retrieved 2022-02-28.