Desmond Màjẹkòdùnmì
Desmond Òlùmùyiwá Màjẹkòdùnmì (A bini óṣu June, Ọdun 1950) jẹ ònimọ nipa ayika ti ilẹ Naijiria[1][2]. Desmond jẹ alaga ti ipinlẹ Lekki ti igbo ilu, Ipinlẹṣẹ Ibugbe awọn ẹranko[3][4] ati olugbalejo ti redio ti Green hour lori iroyin Naijiria 99.3 FM. Màjẹkòdùnmì jẹ̀ ounkọwe, olorin, àgbẹ ati óṣèrè lọkunrin[5][6][7].
Desmond Majekodumni | |
---|---|
Desmond ni Park ti Lufasi, May 2021. | |
Ọjọ́ìbí | June 1950 Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Olumuyiwa |
Ẹ̀kọ́ | Corona Schools, Ikoyi King's College, Lagos Norwich City University, UK. |
Iṣẹ́ | Conservationist |
Gbajúmọ̀ fún | Environmental and climate change activism |
Notable work | LUFASI Park |
Awards |
|
Ìgbèsi Àyé Desmond
àtúnṣeDesmond jẹ ọmọ ọkunrin Federal Minister Republic ti akọkọ, Oloyé Moses Màjẹ̀kòdunmi ati iyawo rẹ, Nora Màjẹ̀kòdunmi, Òludasilẹ̀ ile iwe ti Corona[8].
Desmond ṣè apéjuwé Ayipada lori afẹfẹ, òjò,ìjì ati ìjì lilè ni agbaye gẹgẹbi awọn amọyè ti ṣè sọtẹlẹ ati nkan ti a rin lọwọ. Ninu ọ̀rọ rẹ, yoo ma lọ si, nkan ti awa eniyan lè ṣè nipe ka gbarukuti[9].
Desmond jẹ agbẹ to gba iwe ẹri lori experimental extension fun ilẹ iṣẹ̀ IITA ni Ilu Ibadan to si tun ṣiṣẹ ni Eto ọgbin ti Màjẹ̀kòdunmi; eyi jẹ igbo to da lori amujoto oko ati didasi ni ilu Eko[10][11].
Ìṣẹ rẹ
àtúnṣeMàjẹkòdunmi jẹ alaga ti Awareness and Fund Raising committee of the Nigeria Conservation Foundation (NCF). Arakunrin naa maa nṣè idanilẹkọ lori ayika, imojuto ati ifarada lori ayipada afẹfẹ[12][13].
Ilè isẹ Redio 99.3 FM iroyin Naijiria maa ngba alejo Desmond lọsẹ eyi ti oloyin pe ni Environment Report. Party ti German Green yan Desmond lati kopa ninu ere agbelewo lori ayipada afẹ̀fẹ ni órilẹ ede Naijiria[14].
Ámi ẹ̀yẹ̀ ati idanilọla
àtúnṣeDesmond Màjẹkòdùnmi ti gba órìṣìrìṣi ami ọla latari iṣẹ takun takun nipa ayika ati nkan ọgbin. Desmond ti gba óriṣirìṣi ami ẹyẹ nipa ayipada afẹfẹ ati imojuto ayika[15].
- Desmond ni a sọ ni àkọni ayika ati ọkunrin ti ọdun fun Tv Silverbird ni ilẹ Naijiria[16].
- Ami ẹyẹ̀ lati ọdọ Paschal Dozie
Awọn Itọkasi
àtúnṣe- ↑ Osaji, Sharon (2022-09-22). "Environmentalist calls for end to pollution". Punch Newspapers. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ Eribake, Akintayo (2011-04-04). "couldn't resist eba - Desmond Majekodunmi". Vanguard News. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ Nigeria, Guardian (2018-04-02). "Majekodunmi’s group urges forest protection to halt climate change". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2023-03-26. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Loving Nature". LUFASI. 2014-12-17. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Desmond Majekodunmi – Channels Television". Channels Television. 2016-07-26. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ Welle, Deutsche (2016-06-07). "Meet the Eco Heroes - Nigeria-Environmental activism in times of economic crisis". DW.COM. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Eco hero Desmond Majekodunmi – DW – 05/21/2016". dw.com. 2016-05-19. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Corona School Gives Girl Second Chance at Education with Six-year Scholarship". THISDAYLIVE. 2020-03-18. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "My Encounter With A Black Mamba – Desmond Majekodunmi". TheInterview Nigeria. 2016-04-04. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "WED2020 – FABE INTERNATIONAL FOUNDATION". FABE INTERNATIONAL FOUNDATION – ….environmental sustainability. 2020-06-07. Retrieved 2023-09-04.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Onuoha, Chris (2020-01-03). "Ben Enwonwu Foundation Point of View: When experts query environmental degradation". Vanguard News. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "How environmentalist shunned financial gains to conserve nature". EnviroNews Nigeria. 2016-04-21. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Desmond Majekodunmi – EnviroNews Nigeria". EnviroNews Nigeria. 2023-09-04. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Rapping For ‘Massive’ Reforestation". Channels Television. 2016-07-26. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ Nwokoji, Chima; Nwokoji, Chima (2023-05-08). "World Earth Day 2023: Environmentalist, Desmond Majekodumi, commends Unity Bank’s sustainability strides". Tribune Online. Retrieved 2023-09-04.
- ↑ "Mr. Desmond Majekodunmi". Naturenews.africa. 2023-09-04. Retrieved 2023-09-04.