Devatop Centre for Africa Development

Devatop Centre for Africa Development jẹ́ àjọ tí àwọn olùdarí wọn jẹ́ ọ̀dọ́ tí àfojúsùn wọn ò dá lórí ajọ̀ àìlérè tó ń gbógun ti kíkó àwọn ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́, ìwà ipá tí orísun jẹ́ ẹ̀yà-ìbí, lílọ ọmọ ní lìlòkulò, fífún àwọn ọmọ tí ó ní àǹfààní ẹ̀kọ́ ní ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ àti dídán àwọn obìnrin àti ọ̀dọ́ lóówò. Àjọ yìí jẹ́ àjọ tó síwájú ní ígbógun kíkó ènìyàn lo sókè òkun lọ́nà àìtọ́, ṣíṣe àwọn ètò ẹ̀kọ́ ní orí lé-èdè Nàìjíríà. Àjọ yìí ti forúkọ wọn lẹ̀ fún àjọ Cooperate Affairs Commission Nigeria àti ní ipa lórí mílíọ̀nù ènìyàn látara ẹ̀kọ́, ìlanilọ́ọ̀yẹ̀, ìrànlọ́wọ́, fífún ni lẹ́bùn àti gbígbé ohun jáde nípa lílo èrò ayárabíàṣá.[1]

Devatop Centre for Africa Development
Mottobringing positive change
TypeNon-profit
NGO
IbùjókòóAbuja, Nigeria
IbùdóNigeria
FounderJoseph Osuigwe Chidiebere

Àjo Devatop Centre bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2013 gẹ́gẹ́ bi National Youth Service Community Development Project láti ọwọ́ Joseph Osuigwe Chidiebere.[2] Lẹ́yìn tí Osuigwe pàdé àwọn ènìyàn tí wọ́n ti lo ipá yìí fún, ó yà á lẹ́nu púpọ nípa àwọn ènìyàn tí ó ti ṣẹlẹ̀ sí ní Orílé-èdè Nàìjíríà, àti wí pé èyi mú u lọ́kàn láti dá àjọ tí ó ma kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwon ọ̀dọ́,àwọn ọmọdé, àwọn onímọ̀ àti àwọn obìnrin nípa ìwà ìbàjẹ́ yìí. Ó fọwọ́ṣọwọ́pọ̀ pẹ̀lu àjọ United Nations Office on Drugs and Crime (UNODC) àti àjọ National Agency for Prohibition of Trafficking in Persons (NAPTIP) láti sẹ iṣẹ́ kọ̀ńp̀á láti dá àwọn ọ̀nà púpọ̀ láti gbógun ti ìwà ìbàjẹ́ yìí.[3] Ní ọdún 2014, ó dá ẹgbẹ́ àwọn ọ̀dọ́ láti ma kọ́ ìpa ribiribi yìí lọ , àti láti mú ìdàgbàsókè bá àjọ Devatop Centre for Africa Development.

Awon itoksi

àtúnṣe
  1. "Devatop Centre For Africa Development". End Slavery Now. Retrieved 15 November 2016. 
  2. "Our Story – Devatop Centre for Africa Development". devatop.org. DCAD. Retrieved 16 November 2016. 
  3. Maduka, Godsmercy (1 November 2016). "Committed to combating human trafficking - Writing.Com". www.writing.com (writing.com). http://www.writing.com/main/view_item/item_id/2101568-Committed-to-combating-human-trafficking?rfrid=dmaker. Retrieved 16 November 2016.