Devyn Nekoda (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù Kejìlá ọdún 2000) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Canada. Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré láti ìgbà èwe rẹ̀, ó sì tún ṣeré nínú fíìmù Scream VI tí wọ́n ṣàgbéjáde ní ọdún 2023.

Devyn Nekoda
Ọjọ́ìbíDevyn Nekoda
12 Oṣù Kejìlá 2000 (2000-12-12) (ọmọ ọdún 24)
Brantford, Ontario, Canada
Iṣẹ́
  • Òṣèrébìnrin
  • oníjó
Ìgbà iṣẹ́2014–present

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n tọ́ Nekoda dàgbà ní ìlú Brantford, Ontario, ibẹ̀ náà ni wọ́n ó ti lọ ilé ìwé.[1] Ó jẹ́ ọmọ ọdún méjì nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ń kọ́ ijó jíjó ní ìlú Simcoe, Ontario.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Marsh, Calum (May 12, 2022). "'Sneakerella' Star Devyn Nekoda Talks Sneaker Culture and Pretending Toronto Is New York". Complex.com. Archived from the original on March 10, 2023. Retrieved March 10, 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Devyn Nekoda". cbc.ca. Archived from the original on March 10, 2023. Retrieved March 10, 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)