Diana C. Zollicoffer (ọjọ́ìbí: 1977) jẹ́ òṣèrébìnrin, olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Seychelle.[1] Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún gbígbe àwọn eré bíi Schmoolie the Deathwatcher, Bridget and Iain àti Forgotten Bayou jáde.[2][3]

Diana C. Zollicoffer
Ọjọ́ìbíDiana C. Zollicoffer
1977
Seychelles
Orílẹ̀-èdèSeychellois
Iléẹ̀kọ́ gígaDuke Ellington School of the Arts
Iṣẹ́Director, producer, actress
Ìgbà iṣẹ́1998–present

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Diana C. Zollicoffer: Acteur". allocine. Retrieved 27 October 2020. 
  2. "Diana C. Zollicoffer". cinando. Retrieved 27 October 2020. 
  3. "About Diana C. Zollicoffer". dizolli2. Retrieved 27 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe