Didius Julianus (Látìnì: Marcus Didius Severus Julianus Augustus;[1] 30 January 133 tabi 2 February 137 – 1 June 193), je Obaluaye Romu fun osu meta ni odun 193. O gun ori ite leyin ti o ti fowo ra latowo awon Eso Praetoria, leyin ti awon wonyi ti sekupa asaju re Pertinax. Eyi lo fa Ogun Abele Romu 193–197 wa. Julianus je lile kuro lori ite, o si bo sowo iku latowo aropo re, Septimius Severus.

Didius Julianus
20th Emperor of the Roman Empire
[[File:
ere Didius Julianus
|frameless|alt=]]
Bust of Didius Julianus
Orí-ìtẹ́28 March – 1 June 193
OrúkọMarcus Didius Severus Julianus
(from birth to accession);
Caesar Marcus Didius Severus Julianus Augustus (as emperor)
AṣájúPertinax
Arọ́pọ̀Septimius Severus
Consort toManlia Scantilla
ỌmọDidia Clara
ẸbíajọbaNone
BàbáQuintus Petronius Didius Severus
ÌyáAemilia Clara



  1. In Classical Latin, Julianus' name would be inscribed as MARCVS DIDIVS IVLIANVS AVGVSTVS.