Diego Armando Maradona (ojoibi 30 October 1960 ni Lanús, Buenos Aires - 2020) je agbaboolu-elese to tifeyinti ara orile-ede Argentina.

Diego Maradona
Nípa rẹ̀
OrúkọDiego Armando Maradona
Ọjọ́ ìbí30 Oṣù Kẹ̀wá 1960 (1960-10-30) (ọmọ ọdún 64)
Ibùdó ìbíLanús, Argentina
Ìga1.65 m (5 ft 5 in)
IpòAttacking Midfielder/Second Striker
Èwe
1969–1976Argentinos Juniors
Alágbàtà*
OdúnẸgbẹ́Ìkópa(Gol)
1976–1981Argentinos Juniors167(115)
1981–1982Boca Juniors40(28)
1982–1984Barcelona36(22)
1984–1991Napoli188(81)
1992–1993Sevilla26(5)
1993Newell's Old Boys7(0)
1995–1997Boca Juniors30(7)
Lápapọ̀490(258)
Agbábọ́ọ̀lù ọmọorílẹ̀-èdè
1977–1994Argentina91(34)
Ẹgbẹ́ tódarí
1994Mandiyú de Corrientes
1995Racing Club
2008–Argentina
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).