Dihininet Demsew Jara ni a bini ọjọ kaarun leelogun, óṣu September, Ọdun 1994 jẹ elere sisa lóbinrin to da lori ayẹyẹ oju ọna[1].

Aṣèyọri

àtúnṣe

Ni ọdun 2009, Demsew kopa ninu marathon ti Alaafia Kosice to si pari pẹlu ipo karun pẹlu wakati 2:48:03[2][3]. Ni ọdun 2016, Demsew ṣoju fun órilẹ ede rẹ ninu Idaji idije ti Marathon ti Agbaye ti IAAF to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver to si gbe ipo kẹjọ[4]. Ni ọdun 2019, Demsew kopa ninu Marathon ti Alaafia to si gbe ipo karun pẹlu wakati 2:48:03.

Itọkasi

àtúnṣe
  1. Demsew Profile
  2. Kosice Peace Marathon
  3. Kosice Peace Marathon
  4. IAAF Half Marathon