Diphallia
Diphallia, penile duplication (PD), diphallic terata, tabi diphallasparatus, jẹ́ ohun àìbójúmu tí kò wọ́pọ̀, leyí tí ọmọ ìkókó maa ní okó méjì. Àkọsílẹ̀ àkọ́kọ́ tí a kọ́kọ́ rí ni tí Johannes Jacob Wecker ní ọdún 1609.[1][2] Ìru nkan báyìí maa ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ní bíi 5.5 million àwọn ọkùnrin ní United States.[3]
Diphallia | |
---|---|
Diphallia | |
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta |
Àwọn àrùn to ní ṣe pẹ̀lú renal, vertebral, hindgut, anorectal tàbí àwọn àrùn abínibí míràn ni ó maa ń rọ̀ mọ́ diphallia. O tún ṣeéṣe kí ènìyàn ní àrùn spina bifida.[2] Àtikú ọmọ tí wọ́n bá bí pẹ̀lú PD àti àwọn àrùn tó rọ̀ mọ́ọ yára púpọ̀ látàrí oríṣiríṣi àrùn tí o maa wọlé sí irú ọmọ bẹ́ẹ̀ lára tí ó sì níí ṣe pẹ̀lú renal tàbí àwọn colorectal system irú ọmọ bẹ́ẹ̀.
A ní ìgbàgbọ́ wípé diphallia maa ń wáyé láti inú oyún láàrín ọjọ́ kẹtàlélógún sí ọjọ́ karùnlélógún.
Àwọn àkíyèsí
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Concealed diphallus :a Case report and review of the literature". Journal of Indian Association of Pediatric Surgeons 5 (1): 18–21. 2000. Archived from the original on 2016-03-03. https://web.archive.org/web/20160303192733/http://www.jiaps.com/article.asp?issn=0971-9261;year=2000;volume=5;issue=1;spage=18;epage=21;aulast=Sharma;type=0. Retrieved 2016-08-08.
- ↑ 2.0 2.1 Mirshemirani, AR; Sadeghyian, N; Mohajerzadeh, L; Molayee, H; Ghaffari, P (2010). "Diphallus: Report on six cases and review of the literature". Iranian journal of pediatrics 20 (3): 353–7. PMC 3446048. PMID 23056729. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3446048.
- ↑ "Indian man wants op to remove extra organ". Reuters. 19 August 2006. Archived from the original on 22 January 2007. Retrieved 2006-08-18.
- ↑ Castillo, Viviana M; Brown, Donald I (2012). "One Case of Triphallia in the Marine Snail Echinolittorina peruviana (Caenogastropoda: Littorinidae)". International Journal of Morphology 30 (3): 791. doi:10.4067/S0717-95022012000300003.
- ↑ Daniel Rosney (6 January 2015)
- ↑ Kory Grow (31 December 2014).
Àwọn ìjápò látìta
àtúnṣe- Chadha R, Bagga D, Gupta S, Mahajan JK. (July 2001). "Complete diphallia associated with features of covered exstrophy." 36 (7): E12, W.B. Saunders Company. National Center for Biotechnology Information, US National Library of Medicine, National Institutes of Health
- Fleishman, Cooper (May 15, 2012). "Man With 2 Penises, Woman With 2 Vaginas Were the Sexiest Couple of the 19th Century". HyperVocal.
- Nelson, Sara C. (Jan 1, 2014). "Man 'With Two Penises' Reveals All On Reddit". Huffington Post
- DoubleDickDude (Jan 2, 2014). "I am the guy with two penises. AMA." Reddit.