Eṣinṣin

(Àtúnjúwe láti Diptera)

Àwọn eṣinṣin jẹ́ kòkòrò ninu ito awon oníyẹ̀ẹ́meji (Diptera; lati ede Griiki di = meji, ati ptera = iye). Iyato won kedere si awon kokoro miran ni esinsin ni iye ifo meji ni aya-arin ati pair of haltere meji, to wa lati iye eyin, ni aya-ikeyin. (Awon irueda esinsin kan yato nitoripe won ko le fo). Awon kokoro miran ti won tun ni iye to unsise ati iru halteres kan ni Strepsiptera, won si yato si awon esinsin nitoripe awon Strepsiptera ni halteres won ni aya-arin ati iye ifo won ni aya-ikeyin.

Eṣinṣin/Eṣin
Anatomy of a Housefly. I: head; II: thorax III: abdomen. — 1: prescutum; 2: anterior spiracle; 3: scutum; 4: basicosta; 5: calypters; 6: scutellum; 7: wing vein; 8: wing; 9: abdominal segment; 10: haltere; 11: posterior spiracle; 12: femur; 13: tibia; 14: spur; 15: tarsus; 16: propleuron; 17: prosternum; 18: mesopleuron; 19: mesosternum; 20: metapleuron; 21: metasternum; 22: Compound eye; 23: arista; 24: antenna; 25: maxillary palps; 26: labium; 27: labellum; 28:pseudotracheae.
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Subclass:
Infraclass:
Superorder:
Ìtò:
Diptera

Suborders

Nematocera (includes Eudiptera)
Brachycera

Aworan iru esinsin orisirisi merindinlogun