Àwọn àdúgbò ilẹ̀ Ghánà

Isakoso pipin ti Ghana
(Àtúnjúwe láti Districts of Ghana)

Awon Adugbo ile Ghana je titungbajo ni 1988/1989 lati mu ise ijoba sunmo awon aralu ati lati koju iwabaje to gbale larin awon onibise. itundajo awon opin 1980 pipinlabe awon Agbegbe ile Ghana si adugbo 110, nibi ti awon ile-igbimo ibile adugbo kookan ti le dojuko isoro imojuto ibile ti won. Ni 2006, awon adugbo 28 tuntun je didasile eyi mu apapo iye awon adugbo de 138. Ni February 2008, awon adugbo miran tun je didasile lati mu iye apapo de 170 ni Ghana.[1]

Districts of Ghana.



E tun wo

àtúnṣe

Awon Agbegbe ile Ghana

Awon orisun

àtúnṣe
  1. "BREAK DOWN OF METROPOLITAN, MUNICIPAL AND DISTRICT ASSEMBLIES IN GHANA" (PDF). GhanaDistricts.com. Archived from the original (PDF) on 2010-02-16. Retrieved 2009-11-23.