Dolapo Oni, tí àwọn ènìyàn mọ̀ nígbà mìíràn sí Marcy Dolapo Oni[1] jẹ́ Òṣèré Nàìjíríà ,[2] Olóòtú, tẹlẹfísọ̀n, aláwòkọ́se àti [3] Mii sí.[4]

Dolapo Oni
Ọjọ́ìbíLagos
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Bristol, United Kingdom
Iṣẹ́TV host, producer, actress, mentor
Olólùfẹ́Adegbite Sijuwade
Parent(s)

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àtúnṣe

Oni jẹ́ ọmọ àbíkẹ́yìn nínu ọmọ mẹ́rin tí àwọn òbí rẹ̀ bí. Ó lo ogún ọdún ní ìlú Aya-ọba kí ó tó padà wá sí ìlú Nàìjíríà ní ọdún 2010.[5] Gẹ́gẹ́ bí ọmọ ọdún mẹ́wàá, ó fẹ́ di Òṣèré lẹ́yìn tí ó wo Andrew Lloyd Webber's musical, Aspects of Love, ní The Oxford Playhouse.

Ó parí ilé-ìwé girama ní Headington School. Ó lọ sí Fáṣítì Bristol níbi tó ti gba oyè ní kẹ́míṣítìrì.[6]

Ayé rẹ̀ àtúnṣe

Oni bẹ̀rẹ̀ sí ní ma ṣeré nígbà tó ń gbé ní ìlú aya-ọba, lẹ́yìn tó parí ẹ̀kọ́ Fáṣítì rẹ̀ látara wí pé ó ń lọ sí ilé-ìwé dírámà. Ó rí àyè láti kẹ́kọ̀ọ́ ní Academy of Live and Recorded Arts (ALRA) ní Wandsworth, London, níbi tí ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, lára wọn ni Walking Waterfall by Nii Ayikwei Parkes, William Shakespeare's A Midsummer Night’s Dream, In Time by Bola Agbaje, God is a DJ àti Iya-Ile (The First Wife by Oladipo Agboluaje. Ó gba oyè lọ́wo the Dorothy L. Sayers Drama Award.

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Alafe, Adebimpe (3 March 2020). "5 ways to rock black as inspired by Marcy Dolapo Oni". Pulse. https://www.pulse.ng/lifestyle/fashion/marcy-dolapo-oni-made-us-want-to-wear-black-all-week-long/1gr71h0. 
  2. "7 things you probably don't know about talented TV host, actress". Pulse. 19 August 2019. https://www.pulse.ng/entertainment/movies/marcy-dolapo-oni-7-things-you-probably-dont-know-about-talented-tv-host-actress/xn3shk8. 
  3. "Mum Of The Month – Marcy Dolapo Oni". LagosMums. 20 March 2019. https://lagosmums.com/lagosmums-mum-of-the-month-marcy-dolapo-oni/. 
  4. Bilen-Onabanjo, Sinem (20 August 2016). "Princess Charming: Dolapo Oni". The Guardian. https://guardian.ng/guardian-woman/princess-charming-dolapo-oni/. 
  5. "COVER STORY – DOLAPO ONI". Lady Boss. 27 May 2017. Archived from the original on 3 March 2021. https://web.archive.org/web/20210303055702/http://ladybossmag.ladybiba.com/2017/05/post-interview/. 
  6. "Why I left Moments with Mo – Dolapo Oni-Sijuwade". Punch. 3 April 2016. Archived from the original on 1 February 2020. https://web.archive.org/web/20200201122426/https://punchng.com/why-i-left-moments-with-mo-dolapo-oni-sijuwade.