Dolly Unachukwu

Òṣéré orí ìtàgé

Dolly Unachukwu (tí a bí ní 1 Kọkànlá Oṣù 1969) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, agbéréjáde, ònkọ̀wé, àti olùdarí. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹni-ìṣáájú ti Nollywood. Ó gbajúmọ̀ káárí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bi Fadake Akin-Thomas nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Fortunes.[2]

Dolly Unachukwu
Ọjọ́ìbíDolly Nchedo Nkem Unachukwu
Oṣù Kọkànlá 1, 1969 (1969-11-01) (ọmọ ọdún 54)
Lagos, Nigeria
Iṣẹ́Actress, writer, producer, film director
Ìgbà iṣẹ́1986 - present
Olólùfẹ́Emmanuel Nwokenkwo (1992 - 1994) (divorced) 1 child
Jonathan Ezea (2000 - 2000) (annulled)
Dr. Olaniyan (2011-present) [1]

A bí Dolly Unachukwu ní ọdún 1969 sí ìdílé eléyàn méje kan. Unachukwu bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìndínlógún. Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Amichi ní Ìpínlẹ̀ Anámbra.

Àkọ́kọ́ ìfihàn rẹ̀ nínu eré wáyé ní ọdún 1985 níbi tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé. Lẹ́yìnwá ìgbà náà ló kópa nínu eré Mirror in the Sun gẹ́gẹ́ bi Prisca.

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ àtúnṣe

  • Mirror in the Sun (TV) 1986
  • Fortunes (TV) 1993
  • Deadly Affair 1995 1&2 1994
  • Glamour Girls 2 1995
  • Tears for Love 1996
  • Deadly Affair II 1997
  • Deadly Passion 1997
  • Wildest Dream 1997
  • Love without Language 1998
  • Brotherhood of Darkness 1998
  • Father Moses 1999
  • Full Moon 1 & 2 1999
  • War of Roses 2000
  • The Empire 2005
  • Sisters Love 2007

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe