Donald Okogbe
Okogbe Ojemeh Donald jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o jẹ ọmọ ẹgbẹ ti o nsójú Akoko-Edo II ni Ile-igbimọ Aṣòfin Ìpínlè Edo . [1]
Ni Oṣu Kẹwa Ọdun 2024, oṣu mẹfa lẹhin idaduro rẹ ni May 2024, Ile-igbimọ Aṣofin Ìpínlẹ̀ Edo da Okogbe pada sipo lẹhin ẹsun kan pe o ti gbìn awọn ogún si ile apejọ naa. [2] [3] [4]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://tribuneonlineng.com/edo-assembly-my-suspension-cannot-stand-hon-okogbe/#google_vignette
- ↑ https://dailytrust.com/suspended-edo-lawmaker-sues-speaker-over-allegation-of-planting-charms-in-assembly-complex/
- ↑ https://dailypost.ng/2024/10/02/edo-assembly-recalls-3-suspended-lawmakers/
- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2024/05/06/edo-assembly-suspends-three-lawmakers-over-alleged-plot-to-remove-leadership/#google_vignette