Donna Summer
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Donna Summer (oruko abiso LaDonna Adrian Gaines) (December 31, 1948 – May 17, 2012)[1] je akorin ati akoweorin ara Amerika to gbajumo nigba asiko disco ni opin ewadun 1970s. O gba Ebun Grammy ni emarun, Summer je olorin akoko to ni awo-orin meta to de ipo kinni ni Amerika lori atojo Billboard, be sini o tun ni orin merin ni ipo kinni larin osu 13.
Donna Summer | |
---|---|
Donna Summer in 2009 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | LaDonna Adrian Gaines |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Donna Gaines |
Ọjọ́ìbí | Boston, Massachusetts, U.S. | Oṣù Kejìlá 31, 1948
Aláìsí | May 17, 2012 Naples, Florida, U.S. | (ọmọ ọdún 63)
Irú orin | Pop, disco, dance, rock, R&B |
Occupation(s) | Singer, songwriter |
Instruments | Vocals, piano |
Years active | 1968–2012 |
Labels | Oasis, Casablanca (1975–80), Geffen (1980–88), Atlantic (1988–91), Mercury (1994–96), Warner-Elektra-Atlantic (1980–91), Epic (1999–2001), Burgundy (2006–12) |
Associated acts | Giorgio Moroder, Brooklyn Dreams |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ [[[:Àdàkọ:Allmusic]] allmusic ((( Donna Summer > Biography )))]