Dorcas Venenge Agishi
Dorcas Venenge Agishi (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin ọdún 1961), jẹ́ Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A bí i ní Wukari, ní ìlú Taraba. Ó wá láti ìpínlẹ̀ Benue, àti pé ó jẹ́ ìyàwó sí Solomon Agishi tí ó wá jẹ́ ọkọ rẹ̀. [1]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ "AGISHI, Dorcas Venenge". Biographical Legacy and Research Foundation. 2020-01-06. Retrieved 2023-03-12.