Doreen Awuah
Doreen Angelina Awuah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 12, óṣu December ni ọdun 1989. Agbabọọlu naa ṣere fum awọn ọdọmọbinrin Ghatel gẹgẹbi midfielder[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Doreen Angelina Awuah | ||
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kejìlá 1989 | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | 1 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Doreen kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2007[2].