Doris Anyango
Doris Anyango jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 19, óṣu November ni ọdun 1993. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ́bi defender[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Doris Anyango Ogiro | ||
Playing position | defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Spedag | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Doris kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica to waye ni ọdun 2016[4].