Dosu Joseph

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Joseph Dosu tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kẹfà ọdún 1973 (19th June 1973) ní ìlú Àbújá, Olú ìlú orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Àgbádárìgì ní ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2] Dosu Joseph wà lára àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Òlíḿpííkì fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n gba àmìn ẹ̀yẹ wúrà ní Atlanta lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 1996. [3]

Joe Dosu
Personal information
OrúkọJoseph Dosu
Ọjọ́ ìbí19 Oṣù Kẹfà 1973 (1973-06-19) (ọmọ ọdún 51)
Ibi ọjọ́ibíAbuja, Nigeria
Ìga6 ft 4 in (1.93 m)
Playing positionGoalkeeper
Club information
Current clubWesterlo Football Academy (Head coach)
Youth career
until 1990Julius Berger
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1991–1996Julius Berger
1996–1998Reggiana0(0)
National team
1996–1997Nigeria3(0)
Teams managed
2009–Westerlo Football Academy
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún Nàìjíríà Nàìjíríà
Men's Football
Wúrà 1996 Atlanta Team Competition

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. PeoplePill (1973-06-19). "Dosu Joseph: Footballer - Biography, Life, Family, Career, Facts, Information". PeoplePill. Retrieved 2020-01-06. 
  2. "Dosu Joseph Archives". Latest Sports News In Nigeria. Retrieved 2020-01-06. 
  3. "Dosu Joseph Biography, Age, Height, Net worth, Son, Daughter, Family". CurataGraphy. 1973-06-19. Retrieved 2020-01-06. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]