Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the Oba of Lagos. Fún other people, ẹ wo: Dosunmu (surname).

Dosunmu (1823 – 1885), tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Docemo, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà ní àkọsílẹ̀ ní ìwé ìlú ayaaba ṣe ìjọba rẹ̀ ní ìlú Èkó láti ọdún 1853 lẹ́yìn ìgbà tó joyè lẹ́yìn ikú bàbá rè Ọba Akitoye,[1] títí di ìgbà tó fi kú ní ọdún 1885.[2] Ó sá lọ sí ìlú ayaaba ní oṣù kẹ́jọ ọdún 1861 nènìyànwí pé àwọn ènìyàn lé pa á

Dosunmu
Reign 1853–1885
Coronation 1853
Predecessor Akitoye
Successor Oyekan I
Father Akitoye
Born c. 1823
Lagos
Died 1885 (ọmọ ọdún 61–62)
Lagos
Burial Lagos


Bó ṣe jọba

àtúnṣe

Dí oòuùmuúaṣe gu orí oyè kò sí ní ìlànà pẹ̀lú bí ọba ṣe yẹ kó jẹ ní ìlú Èkó nítorí wí pé àwọn àjọ Ìlú ayaaba ló fi sí orí oyè. Orúkọ ẹni tó fi sí orí oyè gan-an jẹ́ Benjamin Campbell. Èyí ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ìlú ayaaba dá sí ọ̀rọ̀ Ìlú Èkó ní Oṣù Kejìlá ọdún 1851. iampbell htí gbọ́ nípa ikú Ọba Akítóyé ní ọjọ́ kejì oṣù kẹsàn-án ọdún 1853 láti ọwọ́ C.C Gollmer tó ń bá CMS ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n kò sọ fún àwọn afọbajẹ. Ohun tó bèrè lọ́wọ́ wọn ni wí pé tá ni ó yẹ àròlélỌba Akítóyé eẹ́yìn tó bá wàjà. Gbogbo afọbajẹ gba wí pé Dòsùnmú náà ni oyè tó sí lẹ́yìn bàbá rẹ̀. Ọjọ́ kejì ọjọ́ náà ni Ọba Dòsùnmú gùn orí ipò àwọn bàbá rẹ̀[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Akyeampong, Emmanuel Kwaku; Gates, Henry Louis (2012). Dictionary of African Biography. 6. OUP USA. p. 148. ISBN 9780195382075. https://books.google.com/books?id=39JMAgAAQBAJ&pg=PA148&lpg=PA148&dq=akitoye+died+1853. Retrieved 26 November 2016. 
  2. Cole, Patrick (17 April 1975). Modern and Traditional Elites in the Politics of Lagos. Cambridge University Press, 1975. p. 170. ISBN 9780521204392. https://archive.org/details/moderntraditiona0000cole/page/170. 
  3. Smith, Robert (January 1979). The Lagos Consulate, 1851-1861. University of California Press, 1979. p. 55. ISBN 9780520037465.