Dres the rapper
Andres "Dres" Vargas-Titus) (ọjọ́ ìbí jẹ́ oṣù kẹta, ọjọ́ kejidinlogun, ọdún 1967) jẹ́ Òṣeré Hip hop ni orile Ede Amerika. Ó jẹ́ olori fún àwọn Òṣeré tí orúkọ ègbé wọn jẹ́ Alternate Hip hop duo Black sheep group, kí ó tó dá dúró.
Dres | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Andres Vargas-Titus |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Dres |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹta 1967 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Queens, New York, U.S. |
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) | Rapper, actor |
Years active | 1989–present |
Labels | Mercury/PolyGram Records Ground Control Records Tommy Boy Entertainment |
Associated acts | Black Sheep Native Tongues |
Ìṣe
àtúnṣeDres dá egbe Black sheep kalẹ ni 1989 pẹ̀lú Mista Lawnge. Àwọn mejeeji kọ́kọ́ ṣeré papọ ni 1991 tí wọn pé àkọlé orin wọn ní De La Soul. Ó kópa ńinu àwo orin tí àkọlé rẹ jẹ "Fanatic of The B word.[1]
Àtòjọ orin àdákọ
àtúnṣeÀwo-orin
àtúnṣeAlbum information |
---|
Sure Shot Redemption
|
From the Black Pool of Genius: the Prelude
|
From the Black Pool of Genius
|
Àwọn orin àjọkọ
àtúnṣe- "Fanatic Of The B Word" by De La Soul, from its 1991 album De La Soul Is Dead.
- "Work To Do" by Vanessa L. Williams, from her 1991 album The Comfort Zone.
- "Let The Horns Blow" by Chi Ali, from his 1992 album The Fabulous Chi-Ali.
- "Roll Wit Tha Flava" by the Flavor Unit MCs, from the 1993 album Roll Wit Tha Flava.
- "En Focus" by De La Soul, from its 1993 album Buhloone Mindstate.
- "First...and Then" by Handsome Boy Modeling School from its 2004 album White People.
- "Foolin' Around" by Rhymefest from his 2008 mixtape Man in the Mirror.
- "React with a mic" by Twista from his 1994 album Resurrection
- "Back on the Scene" By Slaughterhouse from its 2011 Slaughterhouse EP
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Who's the Man? (1993) bíiMalik
- Once in the Life (2000) bíi Hector
- "Words Up!" a CBS Schoolbreak Special, Season 10, Episode 2 (1992) bíiAeschylus