Drug Trafficking in Nigeria

Òwò gbígbé oògùn-olóró lọ sí ilẹ̀ mìíràn láti tà á jẹ́ ẹ̀sẹ̀ tó lágbára ni Orílé èdè Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ló rí iṣẹ́ yìí bí i òwò tó lérè lóri. Àwọn Ọ̀daràn ènìyàn ló máa ń ṣiṣẹ́ yìí. Èyí fi hàn wí pé kò kì í ṣe àwọn nìkan lọ máa ń mú lọ sókè òkun láti fi ṣìwò burúkú yìí. Èyí ti di ohun ìbàjẹ́ láwùjọ wa débi wí pé àwọn ènìyàn tí à ń fi ojú wò gan-an ti ń ṣe é. Àwọn ènìyàn bí àlùfáà, páṣítọ̀ àti àwọn ènìyàn ńláńlá mìíràn.[1]

Òwò yìí ti jẹ́ ọ̀nà kíkówójọ fún  àwọn ọ̀wọ́ Ọ̀daràn púpọ̀, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọwọ́ yìí tì ń kópa nínú àwọn ìwà ìbàjẹ́ bí i Dídigunjalè, Sísọ àwọn ọmọ ènìyàn di Ẹrú àti ẹ̀ṣẹ̀ Onírìnàjò láti ìlú kan sí òmíràn.[2]

Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The Meaning of Drug Trafficking; Reasons for Trafficking in Drugs". ClassHall.com. 2019-04-22. Archived from the original on 2022-05-05. Retrieved 2022-03-31. 
  2. "Drug trafficking". National Crime Agency. 2022-03-30. Retrieved 2022-03-31.