Dutse
Olú-ìlú ìpínlè Jigawa, Nàìjíríà
Dutse ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Jigawa ní Ariwa Nàìjíríà. Ibẹ̀ ni Yunifásitì ìlú Dutse tí wón dá kalẹ̀ ní oṣù kọkànlá ọdún 2011kalẹ̀ sí. Àwọn olùgbé Dutse jẹ́ 153,000,[1] òun sì ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ Jigawa.
Dutse | |
---|---|
Àwòrán ìgboro ní ìlú Dutse | |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ipinle | Ipinle Jigawa |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Dutse". World Gazetteer. Stefan Helders. Archived from the original on 2013-02-10. Retrieved 2007-02-18. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)