Dwayne Johnson
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Dwayne Douglas Johnson (ojoibi May 2, 1972), to tun gbajumo pelu oruko ijaemu re The Rock, je osere, olootu, onisowo, ajaemu totifeyinti ati agbaboolu-elese ti Amerika ara Amerika[1] [2].[1] O je ajaemu fun ile-ise World Wrestling Federation (WWF, loni bi WWE) fun odun mejo ko to di osere. Awon filmu re ti pawo to to US$3.5 billion ni Amerika ati US$10.5 billion lagbaye,[3] to so di ikan ninu awon osere to pawo filmu julo ni gbogbo igba aye.[4]
Dwayne Johnson | |
---|---|
Johnson in March 2013 | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kàrún 1972 Hayward, California, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | Canadian[1] • American |
Iṣẹ́ | Actor, producer, businessman, professional wrestler, football player |
Ìgbà iṣẹ́ | 1990–1995 (football) 1996–2004; 2011–2019 (wrestling) 1999–present (acting) |
Olólùfẹ́ | Dany Garcia (m. 1997; div. 2007) Lauren Hashian (m. 2019) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn olùbátan | Rocky Johnson (father) Peter Maivia (grandfather) Lia Maivia (grandmother) Nia Jax (cousin) Rosey (cousin) Roman Reigns (cousin) Sib Hashian (father-in-law) |
Àdàkọ:Infobox professional wrestler |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Gill, Meagan (June 13, 2017). "Proud of Canadian roots: Dwayne "The Rock" Johnson holds dual-citizenship" (in en). 604 now. https://604now.com/canadian-roots-the-rock-dual-citizenship/.
- ↑ "Dwayne "The Rock" Johnson Misses Wrestling" – via www.youtube.com.
- ↑ "Dwayne Johnson Movie Box Office Results". Box Office Mojo. Retrieved September 11, 2019.
- ↑ "People Index". Box Office Mojo. Retrieved September 11, 2019.