Ewì Ọmọdẹ́ - Ẹyẹ mélòó tolongo wáyé
(Àtúnjúwe láti EWÌ ỌMỌDÉ - ẸYẸ MÉLÒÓ TOLONGO WÁYÉ?)
EWÌ ỌMỌDÉ - ẸYẸ MÉLÒÓ TOLONGO WÁYÉ?
Ẹyẹ mélòó tolongo wáyé............. Tolongo
Ọ̀kan dúdú aró...................... Tolongo
Ọ̀kan rẹ̀rẹ̀ osùn..................... Tolongo
Ṣó ṣò ṣó fìrù balẹ̀................. Ṣó ò
Ṣó ṣò ṣó fìrù balẹ̀................. Ṣó ò
Ṣó ṣò só fìrù balẹ̀................. Ṣó ò