Eagle (Ẹyẹ Àṣá)
Taxonomy not available for Accipitridae; please create it automated assistant
Ẹyẹ Àṣá jẹ́ ẹyẹ tí ó ma ń pa àwọn ẹranko kékèké tàbí ẹja inú omi jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ. Àṣá jẹ́ ìkan ninú ìran àwọn ẹyẹ tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pe ní Accipitridae. Ẹ̀yà àwọn ìran ẹyẹ yí tó 68 tí wọ́npọ̀ sí àwọn agbègbè bíi Eurasia and Africa.[1] yàtọ̀ sí àwọn agbègbè tí a mẹ́nubà yí, ẹ̀ya mẹ́rìnlá Outside ọ̀tọ̀ ni ó tún wà tí a sì lè rí méjì ní apá North America, nígbà tí a lè rí ẹ̀yà orísi mẹ́sànán ni apá Central and South America, àti mẹ́ta ní apá ilẹ̀ Australia.
Eagle | |
---|---|
From left to right: golden eagle (Aquila chrysaetos), brown snake eagle (Circaetus cinereus), solitary eagle (Buteogallus solitarius), black eagle (Ictinaetus malaiensis) and African fish eagle (Haliaeetus vocifer). | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Species | |
See text |
Àṣá kìí ṣe ìran ẹyẹ kan bí kò ṣe gbogbo ẹyẹ tí ó bá ń pa ẹranko tàbí àwọn ẹyẹ ẹgbẹ́ rẹ̀ jẹ.
Àwọn itọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ del Hoyo, J.; Elliot, A. & Sargatal, J. (editors). (1994). Handbook of the Birds of the World Volume 2: New World Vultures to Guineafowl. Lynx Edicions. ISBN 84-87334-15-6