Earl F. Hilliard

Olóṣèlú

Earl F. Hilliard jẹ́ ẹni tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹrin ọdún 1942, ó jẹ́ Òṣèlú ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti orílè-èdè U.S. Alabama tó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Igbá-kejì rẹ̀, ní ìgbèríko keje ni Ìpínlẹ̀ orílè-èdè Amẹ́ríkà. [1]

Earl F. Hilliard

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bí Hilliard ní Birmingham, Alabama, ó sì kàwé gboyè ní ilé ìwé Morehouse College.


  1. "Earl Frederick Hilliard". house.gov. Retrieved November 16, 2017.