Eba
Ẹ̀bà jẹ́ óúnjẹ ní ilẹ̀ Yorùbá àti àwọn ẹ̀yà míràn tó yí wọn ká.Ẹ̀bà nínú àwọn ẹ̀yà óúnjẹ tí a mọ̀ sí òkèlè ní èdè Yorùbá, (Swallow) ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn Yorùbá àti àwọn ẹ̀yà míràn tó yí wọn ká fẹ́ràn ẹ̀bà pàápàá jùlọ àwọn àgbàlagbà nítorí wípé ó ma ń tètè yóni, kìí sì í tètè dà nínú ẹni,ẹ̀bà kìí ṣe óúnjẹ tí ń gbani lákòókò tàbí fúni ní wàhálà láti pípèsè tàbí jíjẹ. Ṣíṣe Ẹ̀bà aàrí ni wọ́n ma ń fi tẹ́bà, nígbàtí wọ́n yọ gaàrí látara ẹẹ̀gẹ́tàbí pákí tàbí gbágùúdá tí a lọ̀, tí a sìfún omi inú rẹ̀ gbẹ ṣe.[1]
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "What is Eba - How to Prepare Garri". All Nigerian Foods. Retrieved 2019-01-10.