Èdè Ìgbìrà
(Àtúnjúwe láti Ebira language)
Èdè Igbìrà tàbí Ebira tàbí Egbira jẹ́ èdè ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Kwárà àti Ẹdó àti Násáráwá). Èdè Igbìrà Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Naìjírìà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù kan. Wọn wà ní àgbègbè Èbìrà ní ìpínlè Kogi, Kwara, Edo, àti béè béè lo. Àwon èka èdè tí ó wà ní abẹ́ rẹ̀ ni Okene (Hima, Ihima) ìgbàrà (Etunno) Èbìrà ní ìsupò èka èdè, wón ń lò ó ní ilé ìwé.
Ebira | |
---|---|
Sísọ ní | Nàìjíríà |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 1989 |
Agbègbè | Ìpínlẹ̀ Kwárà, Ìpínlẹ̀ Ẹdó, Ìpínlẹ̀ Násáráwá |
Ẹ̀yà | Àwọn Ebira |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 1,000,000 |
Èdè ìbátan | Niger-Kóngò
|
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | igb |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |