Èbúté-Mẹ́ta jẹ́ agbèègbè ìlú èkó, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Máàpù 1962 tí ó ń ṣe àfihàn Ebute Metta ní Gúúsù.
Ìjúwe ọ̀nà ní Ebute Metta
Ilé tí wọ́n kọ sí Ebute Metta.

Orúkọ

àtúnṣe

Èbúté Mẹ́tajẹ́ ọ̀rọ̀ Yorùbá fún ibi tí ó jẹ́ etí òkun mẹ́ta.[1] Èbúté túmọ̀ sí etí òkun tí mẹ́ta sì túmọ̀ sí mẹ́ta

Wọ́n mọ Ebute Metta sí ṣíṣètò oúnjẹ àti àwọn aṣọ. Ó jẹ́ ibìkan ní ìlú èkó tí ó ti wà tipẹ́,ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé tí ó wà níbẹ̀ ni wọ́n ti kọ́ ní ìgbà ìletò àkọ́kọ́, tí wọ́n sì kọ́ àwọn ilé tí ó wà níbẹ̀ bi èyí tí ó wà ní orílẹ̀ èdè Brazil. Àwọn àyíká rẹ̀ ni ilé ìjọsìn St Jude àti ilé ìwé African Salem School àti ilé ìjọsìn Salvation Army. Gbọ̀gán Lisabi  jásí àyíká Okobaba àti ọ̀sà.

Àwọn ilé tí ó wà níbẹ̀

àtúnṣe

Èbúté Mẹ́ta ní àwọn ilé tí ó lókìkí àti olúilé iṣẹ́ Nigerian Railway Corporation, ilé ìfìwé ránṣẹ́, ilé ìjọsìn St Paul's Catholic, ọjà òyìngbò Oyingbo, ibùdó ọkọ̀, Foucos Secondary School (ilé ìwé tí mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ tẹ́lẹ̀ kọ́), St. Saviour's School,[2] Junior Strides Academy, Ajayi Memorial Hospital, Ebute Metta Health Centre,[3][4] àti àwọn ilé ìtajà oríṣiríṣi. Èbúté Mẹ́ta pín sí méjì: Ìlà-oòrùn àti ìwọ oòrùn.

Ìgbòkègbodò ọkọ̀

àtúnṣe

Èbúté Mẹ́ta jẹ́ ọ̀nà kan tí ó jásí erékùṣù mẹ́ta tí  Victoria, Ikoyi àti  erékùṣù èkó. Ó tún jẹ́ ọ̀nà kan tí ó já sí àwọn agbègbè kan bí ènìyàn bá ń wa ọkọ̀ láti Iddo.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Aderinto, S.; Osifodunrin, P. (2013). The Third Wave of Historical Scholarship on Nigeria: Essays in Honor of Ayodeji Olukoju. Cambridge Scholars Publisher. p. 312. ISBN 9781443847124. https://books.google.co.uk/books?id=FscwBwAAQBAJ&pg=PA312. Retrieved 2015-12-01. 
  2. AVANTVIEW Solutions Limited - www.avantview.com. "St. Saviour's School, Ebute Metta, Lagos". stsavioursebutemetta.org. Retrieved 2015-12-01.  More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  3. "Ebute Metta Health Centre". lagosstateministryofhealth.com. Archived from the original on 2015-12-08. Retrieved 2015-12-01.  More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  4. "Anxiety mounts over healthcare delivery at FMC Ebute Metta...Union insists on CMD’s removal - Vanguard News". vanguardngr.com. Retrieved 2015-12-01.  More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)

Àwọn ìjápọ̀ látìta

àtúnṣe

 Àwọn ibi tí ó ní ṣe pẹ̀lú Ebute Metta ní Wikimedia Commons