Echicha
Ẹchịcha (tún jẹ́, Achịcha) jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ ẹ̀yà Igbo ní nàìjíríà tí a sè pẹ̀lu kókò, mgbụmgbụ, àti epo pupa. .kókò ẹ̀rùn nígbà tí ó ṣòro láti rí ẹ̀fọ́ tútù ní wọ́n sábà máa ń jẹ ẹ́
A bowl of ẹchịcha | |
Alternative names | Achịcha |
---|---|
Place of origin | Nigeria |
Region or state | Igboland |
Main ingredients | Dried Cocoyam, Mgbụmgbụ |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Ẹchịcha ni a máa ń fi kókò gbígbẹ tí a sè tó gbóná lala àti mgbụmgbụ tí a sè rọ̀, ípa sì po méjèèjì pọ̀ pẹ̀lú ọbẹ̀ tí a fi epo pupa sè ụgba (kóró oil bean tree),[1] àlùbósà, ata tútù, àti iyọ̀.[2]
Tún wo
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ugba: The African Salad". IMDiversity.com. Archived from the original on 21 April 2012. Retrieved 11 July 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Achicha". NigeriaGalleria.Com. Retrieved 11 July 2012.