Eddie Coffie
Eddie Coffie (1959–2015) jé àgbà òsèré ará Ghana, Ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn òsèré orílẹ̀ ède Ghana (GAG) àti olùsọ́àgùtàn. Ó ṣe ìfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn erè oníse ilẹ̀ Ghana bí "Bob Smith's Diabolo, Dirty Tears Sinking Sands ati A Northern Affair" .
Iṣẹ́
àtúnṣeNí ọdún 1992, Coffie fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníse ti ilẹ̀ Ghana bí Bob Smith's Diabolo, tí ó kó ipa àkọ̀kọ̀ gẹ́gẹ́bí pásítọ̀-ejò tí ó yípadà sí ẹ̀dá àjèjì tí ńjẹ ẹyin tútù tí ó sì ní ìpèníjà ọpọlọ. [1] Ó tẹ̀síwájú láti hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré oníse bí "Dirty Tears" ní ọdún 1996, Dangerous Game II" àti "The Suspect" ní ọdún 1997. [2] Ó sì tún wà nínú àwọn eré oníse "Sinking Sands ní ọdún 2011 àti "A Northern Affair" ní ọdún 2014[3]tí ó ti gba ààmí ẹ̀yẹ. Ní ọdún 2014, ó tún wà nínú eré àpapọ̀ Ghana àti Nàìjíríà "My Taxi Soul" pẹ̀lu Martha Ankomah, Kalsoume Sinare ati Eddie Watson .
Àwọn òṣèré Ghana
àtúnṣeNí Oṣù Kẹ̀wá Ọdún 2014, a yan Coffie gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ àwọn òsèré orílẹ̀ ède Ghana lẹ́yìn tí ó mú ìbò mẹ́tàlélàádọ̀rún nínú mẹ́rìndínlàádọ̀sán[4][5]. Ó jẹ́ ààrẹ ẹgbẹ́ náà tí ọlọ́jọ́ fi dé ní ọdún 2015. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àjọ tó ṣe ìkéde àsà pẹ̀lú tí òsèré àti olósèlú Dzifa Gomashiejẹ́ ààrẹ wọn ní ilẹ̀ Ghana[6][7]. Látàrí ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ààrẹ GAG, ó sisẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì pẹ̀lú Ààrẹ GHAMRO Kojo Antwi àti Ààrẹ MUSIGHA Bice Obour láti rí wípé àwọn òsèré mọ̀ nípa ìṣedúró ní ilẹ̀ Ghana.
Eré tí o tí kópa
àtúnṣe- Diabolo (1992)[8][9][10]
- Fatal Decision (1993)[11]
- Who Killed Nancy? (1995)[11]
- Sarah II (1995)[11]
- Candidates for Hell (1996)[12][11]
- Dirty Tears (1996)[11]
- Dangerous Game II (1997)[11]
- The Suspect (1997)[11]
- Burning Desire 2 (2002)
- Sinking Sands (2011)
- Burning Desire 3 (2012)
- Burning Desire 4 (2012)
- The Power of Buttocks (2013)[13]
- A Northern Affair (2014)[14]
- My Taxi Soul (2014)[15]
- My Taxi Soul 2 (2014)
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeCoffie ní ọmọ mẹ́ta; ọmọkùnrin méjì àti ọmọbìnrin kan. Ní ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kẹ̀wá ọdún 2015, ó kú látàrí ẹ̀jẹ̀ ríru ní Ilé- ìwòsàn Ridge . A sín ní ọjọ́ kọkàndìnlógún Oṣù kejìlá ọdún 2015,tí ètò ìsìnkú ìkẹhìn rẹ̀ wáyé ní Azumah Nelson Sports Complex, Kaneshie. [16] Pẹ̀lú ojúṣe àti ipa tí ó kó sí ìṣe àti àsà nìnú eré ìtàgé, ìsìnkú ọlọ́lá ni ìjọba orílẹ̀ ède Ghana fi dáa lọ́lá nípasẹ̀ àwọn alákóso fún arìnrìn àjò, àsà àti ìṣe tí alákóso Elizabeth Ofosu-Agyareàti igbá kejì rẹ̀ Dzifa Gomashiesì kópa àti ṣojú ìjọba níbi ìsìnkú náà.
Àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ akọrin àti òsèré jààkànjààkàn b́i Nii-Odoi Mensah, Rose Mensah (Kyeiwaa), Prince Yawson (Waakye) and Augustine Abbey (Idikoko) Bill Asamoah, Emelia Brobbey, Grace Nortey, Kojo Dadson, Kalsoume Sinare and Barima Sidney.[17]ni ó wá síbi Ìsìnkú rẹ́
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe
- ↑ Beck, Rose Marie; Wittmann, Frank (2004) (in en). African Media Cultures: Transdisciplinary Perspectives. Köppe. ISBN 978-3-89645-246-7. https://books.google.com/books?id=iCDxAAAAMAAJ&q=Eddie+Coffie.
- ↑ Anyidoho, Kofi; Gibbs, James (2000) (in en). FonTomFrom: Contemporary Ghanaian Literature, Theatre and Film. Rodopi. ISBN 978-90-420-1273-8. https://books.google.com/books?id=BktpS2StnxQC&q=Eddie+Coffie&pg=PA286.
- ↑ Baylay, Ali. "A Northern Affair – African Movie Star" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-07.
- ↑ Inusah, Mustapha (2014-10-29). "Actor Rev. Eddie Coffie Elected Actors' Guild President". News Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-07. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Addo, Francis (28 October 2014). "Eddie Coffie Is New President Of Actors Guild". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-07. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ghana Culture Forum Task Teams". www.ghanacultureforum.org. Archived from the original on 2021-05-10. Retrieved 2021-05-07.
- ↑ "Ministry meets arts players over GH¢ 1m govt funds". Graphic Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-07.
- ↑ Beck, Rose Marie; Wittmann, Frank (2004) (in en). African Media Cultures: Transdisciplinary Perspectives. Köppe. ISBN 978-3-89645-246-7. https://books.google.com/books?id=iCDxAAAAMAAJ&q=Eddie+Coffie.
- ↑ Barker, Clive (2000) (in en). Extreme Canvas: Hand-painted Movie Posters from Ghana. D.A.P./ Distributed Art Publ.. ISBN 978-0-9664272-2-6. https://books.google.com/books?id=ybsbAQAAIAAJ&q=Eddie+Coffie.
- ↑ "5 classic horror movies Ghanaians used to watch in the 90's". GhanaWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-16. Retrieved 2021-04-28.
- ↑ 11.0 11.1 11.2 11.3 11.4 11.5 11.6 Anyidoho, Kofi; Gibbs, James (2000) (in en). FonTomFrom: Contemporary Ghanaian Literature, Theatre and Film. Rodopi. ISBN 978-90-420-1273-8. https://books.google.com/books?id=BktpS2StnxQC&q=Eddie+Coffie&pg=PA286.
- ↑ Aveh, Africanus (2000-04-26). "Ghanaian Video Films of the 1990s: An Annotated Select Filmography" (in en). Matatu 21-22 (1): 283–300. doi:10.1163/18757421-90000330. ISSN 1875-7421. https://brill.com/view/journals/mata/21-22/1/article-p283_33.xml.
- ↑ Baylay, Ali. "The Power of Buttocks – African Movie Star" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-07.
- ↑ Baylay, Ali. "A Northern Affair – African Movie Star" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-07.
- ↑ "Ghanaian actor passes away". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-11-03. Archived from the original on 2021-05-07. Retrieved 2021-05-07.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:3
- ↑ Online, Peace FM. "Movie Stars Pay Last Respect To Late Eddie Coffie (PHOTOS)". Peacefmonline.com - Ghana news. Archived from the original on 2021-05-07. Retrieved 2021-05-07.