Eddie Tagoe
Eddie Tagoe jẹ́ òṣẹ̀rékùnrin ilẹ̀ Ghana, ó sì gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù, ní ọdún 1970 wọ ọdún 1980.
Eddie Tagoe | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Royal Academy of Dramatic Art |
Iṣẹ́ | actor |
Notable work | Top Secret! Who Is Killing the Great Chefs of Europe? |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeÓ jẹ́ ọmọ olóyè Asafoatsha Ayah Tagoe,[1] olọsì Ìlú London láti lọ kàwé ní pá reflexology kó tó lọ ká ní pá ìwé Òṣeré. Otu gbá owo lọ́wọ́ ìjọba ipilẹ tí Ghana láti lọ ká ìwé ní Royal Academy of Dramatic Act ni ìlú London.[2]