Èdè Gríkì
(Àtúnjúwe láti Ede Griki)
Èdè Gíríìkì jẹ́ èdè àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Gíríìsì àti Kipru. Álífábẹ́ẹ̀tì wọn jáde láti inú Phoenician script tí ó wá padà di ìkọsílẹ̀ fún èdè Látìn, Cyrillic, Armenian, Coptic, Gothic, àti àwọn ìkọsílẹ̀ mìíràn. Láti nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́ta sẹ́yìn ni wọ́n ti ń sọ èdè Gíríìkì ní Balkan peninsula, [4][5] Ẹ̀rí àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ ni Linear B clay tablet tí wọ́n rí ní Messenia tí ọdún rẹ̀ jẹ́ nǹkan bíi 1450 àti 1350 BC,[6] èyí sì ni ó jẹ́ kí èdè Gíríìkì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè tí ó ní àkọsílẹ̀ tó pẹ́ jùlọ.
Greek Gíríkì | |
---|---|
Ελληνικά Ellīniká | |
Ìpè | [e̞liniˈka] |
Sísọ ní | Greece, Cyprus, Greek diaspora. |
Agbègbè | Balkans |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | c. 15 million |
Èdè ìbátan | Indo-European
|
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | el |
ISO 639-2 | gre (B) ell (T) |
ISO 639-3 | variously: grc – Ancient Greek ell – Modern Greek pnt – Pontic Greek gmy – Mycenaean Greek gkm – Medieval Greek cpg – Cappadocian Greek tsd – Tsakonian Greek |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Greek". Office of the High Commissioner for Human Rights. Retrieved 2008-12-08.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 "List of declarations made with respect to treaty No. 148". Council of Europe. Archived from the original on 2012-05-22. Retrieved 2008-12-08.
- ↑ "An interview with Aziz Tamoyan, National Union of Yezidi". groong.usc.edu. Archived from the original on 2009-06-25. Retrieved 2008-12-08.
- ↑ Renfrew 2003, p. 35; Georgiev 1981, p. 192.
- ↑ Gray & Atkinson 2003, pp. 437–438; Atkinson & Gray 2006, p. 102.
- ↑ "Ancient Tablet Found: Oldest Readable Writing in Europe". National Geographic Society. 30 March 2011. Retrieved 22 November 2013.