Edem Atovor jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 10, óṣu april ni ọdun 1994. Arabinrin naa ṣere fun club israeli[1].

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Edem kopa ninu Cup U-17 awọn obinrin agbaye ti ọdun 2008 ati 2010[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/edem-atovor_prs398350/person.shtml
  2. https://ng.soccerway.com/players/edem-atovor/135352/