Edinburgh Zoo, tẹ́lẹ̀tẹ́lè  Scottish National Zoological Park, jẹ́ ọgbà ẹranko fun ìdárayá 82-acre (33 ha) kan tí kò sí fún èrè tí ó wà ní olúìlú Scotland. Wọ́n kọ́ọ ń ọdún 1913, tí ó sì jẹ́ pé Royal Zoological Society of Scotland lónii, ó máa ń gba èrò tí ó ju 600,000 lọ́dọọdún, tí ó sì jẹ́ kí ó jẹ́ ìkejì ibi tí ó lókìkí jùlọ ni Scotland tí wọ́n máa ń san owó làti wọlé[1]

Àwòrán Stanleycrane
Edinburgh Zoo
Date opened1913
LocationEdinburgh, Scotland
Number of species171
Annual visitors>600,000
MembershipsBIAZA, EAZA,WAZA
Major exhibitsGiant pandas, penguins, koalas, chimpanzees, sun bears
Websiteedinburghzoo.org.uk

Tùn wo àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Zoo Beginnings". Edinburgh Zoo. Archived from the original on 28 September 2007. Retrieved 15 June 2007.