Edna Adan Ismail
Edna Adan Ismail (tí wọ́n bí ní born 8 September 1937) jẹ́ agbẹ̀bí, ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, ó sí tún jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ Mínísítà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè, fún orílẹ̀-èdè Somalia[1] láti ọdún 2003 wọ 2006. Òun sì ni ààrẹ ẹgbẹ́ Victims of Torture.[2]
Edna Adan Ismail | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 September 1937 Hargeisa, British Somaliland | (ọmọ ọdún 87)
Ẹ̀kọ́ | Borough Polytechnic, currently London South Bank University |
Iṣẹ́ | Activist |
Gbajúmọ̀ fún | Activist for the abolition of female genital mutilation (FGM) |
Office | 8th Minister of Foreign Affairs |
Predecessor | Mohammad Saed Gees |
Successor | Abdilahi Mohamed Dualeh |
Olólùfẹ́ | Mohamed Haji Ibrahim Egal |
Awards | Templeton Prize (2023) |
Signature | |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹlpẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeÌlú Hargeisa ni wọ́n bí Ismail sí, ní 8 September 1937,[3] ó sì jẹ́ ọmọ oníṣègùn kan.[4] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí ìyá rè bí, àmọ́ méjì kú nínú wọn lásìkò ìbí wọn.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Gettleman, Jeffrey (2 June 2009). "No Winner Seen in Somalia's Battle With Chaos". The New York Times. https://www.nytimes.com/2009/06/02/world/africa/02somalia.html.
- ↑ Topping, Alexandra (23 June 2014). "Somaliland's leading lady for women's rights: 'It is time for men to step up'". The Guardian. https://www.theguardian.com/world/2014/jun/23/somaliland-womens-rights-gender-violence.
- ↑ Skaine, Rosemary (2008). Women Political Leaders in Africa. McFarlane. pp. 54. ISBN 9780786432998.
- ↑ "125th Anniversary - Get Involved - My Cardiff". Cf.ac.uk. Archived from the original on 13 May 2014. Retrieved 10 December 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Why giving birth in the U.S. is surprisingly deadly". National Geographic. 2018-12-13. https://www.nationalgeographic.com/magazine/2019/01/giving-birth-in-united-states-suprisingly-deadly/.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0