Edward Alabi Ajado (ọjọ àkọ́kọ́, oṣu March, ọdún 1929-ọjọ́ kẹrin din lọgbọ́n, oṣu December, ọdún 1980) jẹ eléré ìdíje tí ilẹ Naijiria. Arákùnrin náà kópa nínú ọgọrun mita àti igba mita nínú Olympic tó wáyé ní ọdún 1952[2][3]. Ní ọdún 1956, Ajado kopa ninu Olympic tí ooru ni ọgọrun mita àti mẹrin × ọgọrun mita[4].

Edward Ajado
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí(1929-03-01)1 Oṣù Kẹta 1929
Abeokuta, Nigeria
Ọjọ́aláìsí26 December 1980(1980-12-26) (ọmọ ọdún 51)[1]
Lagos, Nigeria
Sport
Erẹ́ìdárayáSprinting
Event(s)100 metres

Àṣeyọrí Edward Ajado

àtúnṣe

Ní ọdún 1954, Edward kopa ninu ère Comonwealth tí ilẹ British Empire níbi to ti gba ami ọlá tí Fàdákà nínú eré idije sì sá pẹlu Muslim Arogundade, Abdul Karim Amu, ati Karim Olowu tó sì parí pẹlu ipò kẹrin nínú àgbàlá ọgọrun[5][6].

Àwọn Itọkasi

àtúnṣe
  1. Nigeria Year Book. Times Press. 1982. p. 249. https://books.google.com/books?id=wGcuAQAAIAAJ&q=Edward+Alabi+Ajado. 
  2. "Runsewe bemoans constant neglect of Nigerian Olympians". Daily Trust. 2021-06-27. Retrieved 2023-10-06. 
  3. "Edward Ajado Bio, Stats, and Results". Olympics at Sports-Reference.com. 2009-02-11. Archived from the original on 2020-04-18. Retrieved 2023-10-06. 
  4. "Edward Alabi AJADO Biography, Olympic Medals, Records and Age". Olympics.com. 2023-06-12. Retrieved 2023-10-06. 
  5. "Olympedia – Edward Ajado". Olympedia – Main Page. 1929-03-01. Retrieved 2023-10-06. 
  6. Ikhazuagbe, Duro (2017-12-30). "Amelia Ijeoma Okpalaoka: Celebrating the Life of a Sports Icon Who Passed OnNovember 1st – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. Retrieved 2023-10-06.