Edward Irigha Brigidi jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o ṣiṣẹ gẹgẹbi aṣoju ti àgbègbè Nembe ni Ile-igbimọ aṣofin Ìpínlẹ̀ Bayelsa, labe ẹgbẹ òṣèlú All Progressive Congress (APC). [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe