Edwin Gadayi
Edwin Kwabla Gadayi ti a bini ọjọ kẹrinla óṣu february, ọdun 2001 jẹ asare fun ilẹ ghana[1]. Arakunrin naa kopa ninu ere idije ti awọn asare to waye ni Silesia, Poland ni ọdun 2021 nibi to ti wa lara awọn team ọkunrin marun[2][3].
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Edwin Kwabla Gadayi |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kejì 2001 Ashanti Region |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ghana |
Erẹ́ìdárayá | Athletics |
Event(s) | 100 m, 200 m |
Igbèsi Aye Edwin
àtúnṣeGadayi gbe ni Ashanti, Ghana to si lọ si ilè iwè giga ti Cape Caost[4][5].
Aṣèyọri
àtúnṣeỌdun | Idije | Ipó | Ayẹyẹ | Ago | Wind (m/s) | Ibi iṣèrè | Notes |
---|---|---|---|---|---|---|---|
2019 | African Games | Ipo kẹrin | 4 × 100 m relay | 20.92 | Rabat, Morocco | ||
2022 | LOC 2023 Invitational Championship | Ipo Akọkọ | 200m | 20.848 | Cape Coast | ||
Ghana Athletics Association's Open Championship | Ipo Akọkọ | 100m | 10.626 | KNUST Paa Joe Park |
Ni óṣu july, ọdun 2022 Edwin kopa ninu idije apapọ ti 200 meters to waye ni Cape Coast ni iṣẹ̀ju-aaya 20.848[6][7][8]. Edwin gba ami ọla idẹ ninu idije ti U20 ilẹ afirica. Arakunrin naa yege ninu idije ti awọn ajọ asare ilẹ ghana ti ayẹyẹ̀ naa si waye ni Paa Joe Park ni KNUST[9].
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-08. Retrieved 2023-03-08.
- ↑ https://worldathletics.org/athletes/ghana/edwin-kwabla-gadayi-14786172
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-08. Retrieved 2023-03-08.
- ↑ https://mobile.ghanaweb.com/GhanaHomePage/NewsArchive/GUSA-2020-Edwin-Gadayi-beats-Benjamin-Azamati-in-men-s-200m-final-871291
- ↑ https://www.modernghana.com/sports/1170364/edwin-gadayi-shines-at-ashantiba-meet-2022-of.html
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-08. Retrieved 2023-03-08.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-01. Retrieved 2023-03-08.
- ↑ https://www.modernghana.com/sports/1168671/edwin-gadayi-sets-national-record-in-200-meters.html
- ↑ https://ghanaguardian.com/uccs-edwin-gadayi-wins-100m-race-in-gaa-open-championship