Edwin Powell Hubble (November 20, 1889 – September 28, 1953) je atorawo ara Amerika to se alaye bi agbalaaye se ri nipa sisafihan pe awon galaksi miran na wa leyin Galaksi Milky Way wa. Bakanna o tun sawari pe iyi "isele Doppler" (ni pato "redshift") to je kikiyesi ninu light spectra lati awon galaksi miran unposi ni iye si bi galaksi pato kan se jinnasi lati Aye. Ibasepo yi lo unje ofin Hubble, o si fihan pe agbalaaye unfesi.

Edwin Powell Hubble
Ìbí(1889-11-20)Oṣù Kọkànlá 20, 1889
Marshfield, Missouri, U.S.
AláìsíSeptember 28, 1953(1953-09-28) (ọmọ ọdún 63)
San Marino, California
IbùgbéUnited States
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
PápáAstronomy
Ilé-ẹ̀kọ́University of Chicago
Mount Wilson Observatory
Ibi ẹ̀kọ́University of Chicago
University of Oxford
Ó gbajúmọ̀ fúnBig Bang
Hubble's law
Redshift
Hubble sequence
InfluencedAllan Sandage
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síBruce Medal 1938